Ìfihàn 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti láàrin àwọn ọ̀pá fìtílà náà, ẹnìkan tí ó dà bí “ọmọ ènìyàn,” tí a wọ̀ ní aṣọ tí ó kanlẹ̀ dé ẹṣẹ̀, tí a sì fi àmùrè wúrà dì ní ẹ̀gbẹ́.

Ìfihàn 1

Ìfihàn 1:8-20