Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì subú lulẹ̀, ó gbọ́ ohùn tí ó ń fọ̀ sí i pé, “Ṣọ́ọ̀lù, Ṣọ́ọ̀lù, è é ṣe ti ìwọ fi ń ṣe inúnibíni sí mi?”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:1-5