Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù sí dìde, ó sì bá wọn lọ. Nígbà tí ó dé, wọ́n mú un lọ sí ìyará òkè náà: gbogbo àwọn opó sí dúró tì í wọn sọkún, wọ́n sì ń fi ẹ̀wù àti aṣọ tí Dọ́kásì dá hàn án, nígbà tí ó wà pẹ̀lú wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:37-40