Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ-ẹyìn kan sí wà ní Jópà ti a ń pè ni Tàbítà, èyí tí ó túmọ̀ sí Dọ́kásì; obìnrin yìí pọ̀ ni iṣẹ́ oore, àti ìtọrẹ-àánú ṣíṣe.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:31-41