Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ gbé ní òru, wọ́n sì sọ̀ ọ́ kalẹ̀ lára odi nínú agbọ̀n.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:21-33