Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì jẹun, ara rẹ̀ mókun.Ṣọ́ọ̀lù sì wá pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ní Dámásíkù ní ọjọ́ púpọ̀

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:13-20