Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ananíyà sì dáhùn wí pé, “Olúwa mo tí gbúrò ọkùnrin yìí lọ́dọ̀ ọ̀pọ̀ ènìyàn, gbogbo búrukú ti ó ṣe sí àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ ni Jerúsálémù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:10-16