Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ-ẹ̀yìn kan sì wà ní Dámásíkù, tí a ń pè ni Ananíyà! Olúwa sì wí fún un lójúran pé, “Ananíyà!”Ó sì wí pé, “Wò ó, èmi nìyí, Olúwa.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:3-15