Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańgẹ́lì Olúwa sì sọ fún Fílípì pé, “Dìde kí ó sì máa lọ sí ìhà gúsù, sí ọ̀nà ijù, tí ó ti Jerúsálémù lọ sí Gásà.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:22-32