Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Símónì dáhùn, ó sì wí pé, “Ẹ gbàdúrà sọ́dọ̀ Olúwa fún mi, kí ọ̀kan nínú ohun tí ẹ̀yin tí sọ má ṣe bá mi.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:17-27