Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn olùfọkànsìn kan sì gbé òkú Sítéfánù lọ sin, wọ́n sì pohùnréré ẹkún kíkan sórí rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:1-10