Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì fún Ábúráhámù ni májẹ̀mú ìkọlà. Ábúráhámù bí Ísáákì, ó kọ ọ́ ní ilà-abẹ́ ni ijọ́ kẹjọ tí ó bí i. Ísáákì sí bí Jákọ́bù, Jákọ́bù sì bí àwọn baba ńlá méjìlá.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:1-15