Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:56 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí pé, “Wò ó, mo rí ọ̀run ṣí sílẹ̀, Ọmọ Ènìyàn sì dúró ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:48-59