Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọn sì gbọ́ nǹkan wọ̀nyí ọkàn wọn gbọgbẹ́ dé inú, wọn sì payín keke sí i.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:47-60