Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí náà ni ẹni tí ó wà nínú ìjọ ní ijù pẹ̀lú ańgẹ́lì náà tí ó bá a sọ̀rọ̀ ní orí òkè Sínáì, àti pẹ̀lú àwọn baba wa; ẹni ti ó gba ọ̀rọ̀ ìyè láti fi fún wa.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:33-39