Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni ó mú wọn jáde, lẹ́yìn ìgbà tí ó ṣe iṣẹ́ ìyanu àti iṣẹ́ àmì ní ilẹ̀ Íjíbítì, àti ni òkun pupa, àti ni ihà ní ogójì ọdún.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:28-40