Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì sá nítorí ọ̀rọ̀ yìí, ó sì wa ṣe àtìpó ni ilẹ̀ Mídíànì, níbi tí ó gbé bí ọmọ méjì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:26-31