Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nígbà tí Jákọ́bù gbọ́ pé Àlìkámà ń bẹ ni Íjíbítì, ó rán àwọn baba wa lọ lẹ́ẹ̀kínní.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:3-15