Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sì yọ ọ́ kúrò nínú ìpọ́njú rẹ̀ gbogbo. Ó sì fún Jósẹ́fù ní ọgbọ́n, ó sì mú kí ó rí ojúrere Fáráò ọba Íjíbítì; òun sì fi jẹ baálẹ̀ Íjíbítì àti gbogbo ilé rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:3-12