Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù sì béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Wí fún mi, ṣé iye yìí ni ìwọ àti Ananíyà gbà lórí ilẹ̀?”Ó sì wí pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, iye rẹ̀ nìyẹn.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:6-12