Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà wọn sì lọ kúrò níwájú àjọ ìgbìmọ̀; wọn ń yọ̀ nítorí tí a kà wọ́n yẹ láti jìyà nítorí orúkọ rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:40-42