Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí fún wọn pé “Ẹ̀yin ènìyàn Ísírẹ́lì, ẹ kíyèsí ara yín lóhun tí ẹ̀yin ń pète láti ṣe sí àwọn ọkùnrin wọ̀nyí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:32-42