Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n gbọ́ èyí, ọkàn wọn gbọgbẹ́ dé inú, wọ́n gbérò láti pa wọ́n.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:29-39