Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni Ọlọ́run fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ gbé gẹ́gẹ́ bí Ọmọ-aladé àti Olùgbàlà láti fi ìrònúpìwàdà àti ìdàríjì ẹ̀ṣẹ̀ fún Ísírẹ́lì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:26-35