Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọn sì mú àwọn àpósítélì dé, wọn mú wọn dúró níwájú àjọ ìgbìmọ̀; olórí àlúfáà sì bi wọ́n léèrè.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:18-35