Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ìmọ̀ aya rẹ̀ ó yan apákan pamọ́ nínú owó náà, ó sì mú apákan rẹ̀ wá, ó sì fi í lélẹ̀ lẹ́sẹ̀ àwọn àpósítélì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:1-8