Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ní òru, áńgẹ́lì Olúwa ṣí ìlẹ̀kùn túbú; ó sì mú wọn jáde.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:18-25