Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì ti ọwọ́ àwọn àpósítélì ṣe iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu púpọ̀ láàrin àwọn ènìyàn. Gbogbo wọn sì fi ọkàn kan wà ní ìloro Sólómónì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:8-15