Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójúkan náà ó sì ṣubú lulẹ̀ lẹ́sẹ̀ rẹ̀, ó sì kú; àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin sì wọlé wọ́n bá a ní òkú, wọ́n sì gbé e jáde, wọ́n sín in lẹ́bá ọkọ rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:9-15