Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe níjọ kejì, àwọn olórí wọn àti àwọn alàgbà àti àwọn olùkọ́ni ní òfin péjọ sí Jerúsálémù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:1-11