Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ nísinsin yìí, Olúwa, kíyèsí ìhàlẹ̀ wọn; kí ó sì fi fún àwọn ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ láti máa fi ìgboyà ńlá sọ ọ̀rọ̀ rẹ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:28-34