Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n sì ń wo ọkùnrin náà tí a mú láradá, tí ó bá wọn dúró, wọn kò rí nǹkan wí sí i.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:11-21