Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àní, gbogbo àwọn wòlíì láti Sámúẹ́lì wá, àti àwọn tí ó tẹ̀lé e, iye àwọn tí ó ti sọ̀rọ̀, wọn sọ ti ọjọ́ wọ̀nyí pẹ̀lú.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:19-25