Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ǹjẹ́ nísinsìn yìí, ará, mo mọ̀ pé nípa àìmọ̀ ni ẹ̀yin fi ṣe é, gẹ́gẹ́ bí àwọn olórí yín pẹ̀lú ti ṣe.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:13-26