Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin sì pa ìpilẹ̀ṣẹ̀ ìyè, ẹni tí Ọlọ́run sì ti jí dìde kúrò nínú òkú; ẹlẹ́rìí èyí ti àwa jẹ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:9-25