Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí arọ ti a mú láradá sì ti di Pétérù àti Jòhánù mú, gbogbo ènìyàn júmọ́ sure tọ̀ wọ́n lọ ni ìloro ti a ń pè ní ti Sólómónì, pẹ̀lú ìyàlẹ́nú ńlá.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 3:9-14