Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní agbégbé ibẹ̀ ni ilé ọkùnrin ọlọ́lá erékùṣù náà wà, orúkọ ẹni tí a ń pè ní Pọ́bílíù; ẹni tí ó ti ipa inú rere gbà wá sí ọ̀dọ̀ fún ọjọ́ mẹ́ta.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:1-13