Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Tọ àwọn ènìyàn wọ̀nyí lọ, kí ó sì wí pé,“Ní gbígbọ́ ẹ̀yin yóò gbọ́, kì yóò sì yé e yín;à ti ni rírí ẹ̀yin yóò rí, ẹ kì yóò sí òye lati mọ̀.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:18-28