Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ẹlòmíràn gba ohun tí ó wí gbọ́, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹlòmíràn kò sì gbà á gbọ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:18-28