Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì í ṣe oore díẹ̀ ni àwọn alàìgbédè náà ṣe fún wa: nítorí ti wọ́n dáná, wọ́n sì gbà gbogbo wa sí ọ̀dọ̀ nítorí òjò ń rọ nígbà náà, àti nítorí òtútù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:1-4