Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì bu ọlá púpọ́ fún wa; nígbà tí a ń lọ, wọ́n sì fún wa ní ohun púpọ̀ tí a nílò ní ọ̀nà àjò wa.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:1-19