Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí a sì fi agbára káká kọjá rẹ̀, a dé ibi tí a ń pè ní Èbùté Yíyanjú, tí ó súnmọ́ ìlú Láséà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:2-15