Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí a sì ṣíkọ̀ níbẹ̀, a lọ lẹ́bá Kípírúsì, nítorí tí afẹ́fẹ́ ṣọwọ́ òdì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:1-13