Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọn jẹun yó tan, wọn bẹ̀rẹ̀ sí mu ọkọ̀-okun náà fúyẹ́, nípa kíkó àlìkámà dà sí omi.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:35-41