Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ̀ nísinsìn yìí mó gbà yín níyànjú, kí ẹ tújúká; nítorí kí yóò sí ẹni tí yóò nù, bí kò ṣe ti ọkọ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:19-32