Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí a sì ti ń ṣe làálàá gidigidi nínú ìjì náà, ni ijọ́ kejì wọn kó ẹrù-ọkọ̀ dà sí omi láti mú ọkọ̀ fẹ́rẹ̀;

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:12-19