Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà ti ó sì ti gbé ọkọ̀-okun náà, ti kò sì lè dojúkọ ìjì yìí, a fi i sílẹ̀, ó ń gbá a lọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:7-17