Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nítorí pé èbúté náà kò rọrùn láti lo àkókò òtútù níbẹ̀, àwọn púpọ̀ sí dámọ̀ràn pé, kí a lọ kúrò níbẹ̀, bóyá wọn ó lè làkàkà dé Fóníkè, tí i ṣe èbúté Kírétè ti ó kọjú sí òsì ìwọ̀-oorùn, àti ọ̀tún ìwọ̀-oorùn, láti lo àkókò òtútù níbẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 27:10-20