Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èéṣe tí ẹ̀yin fi rò o sí ohun tí a kò lè gbàgbọ́ bí Ọlọ́run bá jí òkú dìde?

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:1-17