Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìn yìí nítorí ìrètí ìlérí tí Ọlọ́run tí ṣe fún àwọn baba wa ni mo ṣe dúró níhìn-ín fún ìdájọ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 26:4-10